Free account: track your progress — Sign up free

BECE Yoruba Language 2023 Objective — Question 102

Question 102 of 120 from the Basic Education Certificate Examination (Junior WAEC) (BECE) Yoruba Language 2023 Objective paper, with the correct answer and a full explanation.

Advertisement

Òdiwọ̀n tí wọ́n lò fún àwọn tí wọ́n yẹ ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ fún ni kíkìdá

  • A. àlejò tí ó bá ti lò ju ọdún mẹ́wàá nílùú.
  • B. àwọn obìnrin tó rẹwà, tí wọ́n sì ń mú yangàn lágbo.
  • C. ọmọ ìlú tó bá jẹ́ ọmọkùnrin tí ó lẹ́wà jùlọ.
  • D. ọmọkùnrin tó mọ nípa iṣẹ́ oko àti ohun ọ̀sìn jùlọ.
  • E. ọmọ tó bá yege jùlọ nínú èdè Òyìnbó, ìṣirò àti iṣẹ́ mẹ́ta mìíràn nínú ìdánwò ti wàyéèkì.Correct

Explanation

Ìdánwò ni wọ́n fi ṣe òdiwọ̀n.

Advertisement

Sign up free to unlock

  • Score tracking
  • Practice history
  • Saved questions
  • Progress dashboard
  • Personalized sessions
  • Weak-topic breakdown

…and/or go further with premium services and No Ads.