BECE Yoruba Language 2023 Objective — Question 105
Question 105 of 120 from the Basic Education Certificate Examination (Junior WAEC) (BECE) Yoruba Language 2023 Objective paper, with the correct answer and a full explanation.
Advertisement
Àbá kí á fi oyè dá àwọn ọmọ ìlú lọ́lá fún ipa pàtàkì tí wọ́n ń kó nílùú wá láti ọ̀dọ̀
- A. Àgùrò
- B. Ìyálóde
- C. Jagun
- D. KábíyèsíCorrect
- E. Olóyè ọ̀tún
Explanation
Kábíyèsí ni olórí ìlú tó ń fi oyè dá ni lọ́lá.
Advertisement
Sign up free to unlock
- Score tracking
- Practice history
- Saved questions
- Progress dashboard
- Personalized sessions
- Weak-topic breakdown
…and/or go further with premium services and No Ads.