BECE Yoruba Language 2023 Objective — Question 33
Question 33 of 120 from the Basic Education Certificate Examination (Junior WAEC) (BECE) Yoruba Language 2023 Objective paper, with the correct answer and a full explanation.
Advertisement
Èwo ni kìí ṣe gbólóhùn alákànpọ̀?
- A. Ìgè jẹ àmàlà, ó tún mu omi síi.
- B. Mo ti bọ ẹran jẹ tán, kí Olú tó dé.Correct
- C. Olú wá, ó sì bámi.
- D. Ó rí wọn ṣùgbọ́n kò mọ wọ́n.
- E. Ó se ọbẹ̀ náà dáradára ṣùgbọ́n kò rí ẹni bá a jẹ ẹ́.
Explanation
Gbólóhùn B ní ọ̀rọ̀ atọ́ka (kí ... tó) tó mú un jẹ́ aláfarahàn, kì í ṣe alákànpọ̀.
Advertisement
Sign up free to unlock
- Score tracking
- Practice history
- Saved questions
- Progress dashboard
- Personalized sessions
- Weak-topic breakdown
…and/or go further with premium services and No Ads.