BECE Yoruba Language 2025 Objective — Question 1
Question 1 of 120 from the Basic Education Certificate Examination (Junior WAEC) (BECE) Yoruba Language 2025 Objective paper, with the correct answer and a full explanation.
Advertisement
ÀKÀYÉ KÌN-ÍN-NÍ Ní ayé àtijọ́, oríṣìíríṣìí ọdẹ ló wà bíi ọdẹ aperin, ọdẹ apẹfọ̀n, ọdẹ apẹja, ọdẹ aṣọ́de, ọdẹ náà sì ni àwọn tí ó ń pa ẹranko kéékèèkè bíi ẹyà, ẹtu, ìgalà àti àwọn mìíràn. Ninú àwọn ọdẹ wọ̀nyí, èyí tí ó le jù lọ ninú wọn ni ọdẹ aṣọ́de nítorí ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ tó ń rin òru ni ó ń ṣọ́. Lára ohun tí ó jẹ́ kí ọdẹ yìí le púpọ̀ ni irinṣẹ́ wọn bíi ìbọn, àdá, ọbẹ, ọfà, òkò àti onírúurú ohun àmúṣagbára bíi egbé, òkígbé, àfẹ̀ẹ̀rì, ajàbọ̀ àti àwọn nǹkan mìíràn tí wọ́n ń lò. Síwájú síi, àwọn ènìyàn tí ọdẹ aṣọ́de ń ṣọ́ kìí ṣe ẹ̀dá lásán, alágbára ni àwọn náà. Nítorí èyí, ẹni tó bá lágbára jù ni ó ń pa ara wọn. Bí ọdẹ aṣọ́de bá ṣe lágbára tó láti lè ṣokọ fún àwọn arínrú yìí ni òkìkí rẹ̀ yóò ṣe kàn tó tí àwọn ènìyàn yóò sì tún máa bẹ̀rù rẹ̀ tó. Orísìí ọdẹ mélòó ni ọ̀nkọ̀wé mẹ́nu bà?
- A. Márùn-únCorrect
- B. Méjì
- C. Mẹ́rin
- D. Mẹ́sàn-án
Explanation
The passage names aperin, apẹfọ̀n, apẹja, aṣọ́de and one more hunter type: five.
Advertisement
Sign up free to unlock
- Score tracking
- Practice history
- Saved questions
- Progress dashboard
- Personalized sessions
- Weak-topic breakdown
…and/or go further with premium services and No Ads.