Free account: track your progress — Sign up free

BECE Yoruba Language 2025 Objective Past Questions

All 120 questions from the Basic Education Certificate Examination (Junior WAEC) (BECE) Yoruba Language 2025 Objective paper, with the correct answer and a full explanation for each. Free, no signup needed.

Advertisement

Yoruba Language 2025 Objective — Question 1

ÀKÀYÉ KÌN-ÍN-NÍ Ní ayé àtijọ́, oríṣìíríṣìí ọdẹ ló wà bíi ọdẹ aperin, ọdẹ apẹfọ̀n, ọdẹ apẹja, ọdẹ aṣọ́de, ọdẹ náà sì ni àwọn tí ó ń pa ẹranko kéékèèkè bíi ẹyà, ẹtu, ìgalà àti àwọn mìíràn. Ninú àwọn ọdẹ wọ̀nyí, èyí tí ó le jù lọ ninú wọn ni ọdẹ aṣọ́de nítorí ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ tó ń rin òru ni ó ń ṣọ́. Lára ohun tí ó jẹ́ kí ọdẹ yìí le púpọ̀ ni irinṣẹ́ wọn bíi ìbọn, àdá, ọbẹ, ọfà, òkò àti onírúurú ohun àmúṣagbára bíi egbé, òkígbé, àfẹ̀ẹ̀rì, ajàbọ̀ àti àwọn nǹkan mìíràn tí wọ́n ń lò. Síwájú síi, àwọn ènìyàn tí ọdẹ aṣọ́de ń ṣọ́ kìí ṣe ẹ̀dá lásán, alágbára ni àwọn náà. Nítorí èyí, ẹni tó bá lágbára jù ni ó ń pa ara wọn. Bí ọdẹ aṣọ́de bá ṣe lágbára tó láti lè ṣokọ fún àwọn arínrú yìí ni òkìkí rẹ̀ yóò ṣe kàn tó tí àwọn ènìyàn yóò sì tún máa bẹ̀rù rẹ̀ tó. Orísìí ọdẹ mélòó ni ọ̀nkọ̀wé mẹ́nu bà?

  • A. Márùn-únCorrect
  • B. Méjì
  • C. Mẹ́rin
  • D. Mẹ́sàn-án

Explanation

The passage names aperin, apẹfọ̀n, apẹja, aṣọ́de and one more hunter type: five.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 3

Èwo ni ó le jù nínú gbogbo àwọn ọdẹ? Ọdẹ

  • A. aperin
  • B. apetu
  • C. apẹfọ̀n
  • D. apẹja

Explanation

The passage says the ọdẹ aṣọ́de is the hardest/strongest of the hunters.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 4

Ọkan nínú àwọn ẹranko kéékèèké tí ó jẹyọ nínú àyọkà yìí ni

  • A. àparò
  • B. asín
  • C. ẹmọ́
  • D. ẹtuCorrect

Explanation

Ẹtu is named among the small animals hunted.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 5

Èwo nínú àwọn wọ̀nyí ni ó jẹ́ ohun àmúṣagbára?

  • A. EgbéCorrect
  • B. Ìbọn
  • C. Ọ̀bẹ
  • D. Ọfà

Explanation

Egbé is listed as an 'ohun àmúṣagbára' (power-giving charm) in the passage.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 6

ÀKÀYÉ KEJÌ “Gbọ́ ìwọ ọmọ mi, máa fi ọgbọ́n pamọ́ dáadáa, dì í sí ọwọ́ òsì rẹ má ṣe fi sí ọwọ́ ọ̀tún kí o má baà fi jẹun. Òdodo ọ̀rọ̀ nìyí, òtítọ́ ni kí o máa sọ”. Bàbá Ọjó ni ó pe ọmọ rẹ̀, Àkànjí, láàárọ̀ kùtù ọjọ́ Ajé láti bá a sọ̀rọ̀ lórí ohun kan tó le mú ènìyàn pegedé nílé ayé. Ó tẹ síwájú ó ní, “Máṣe purọ́ ní ọjọ́ ayé rẹ, òtítọ́ lágbára, agbára rẹ̀ dájú, èké kò ní gbòǹgbò, pẹ̀lẹ́bẹ ni èké máa ń gé elékèé, ó sì máa ń gba iyì lọ́wọ́ ẹni. Bẹ̀rù ikú, bẹ̀rù àárùn, ṣọ́ra fún obìnrin. Féràn ọmọdé àti àgbà, ní kúkúrú, féràn gbogbo ènìyàn ṣùgbọ́n kóríra èké.” Ọ̀rọ̀ yìí ni bàbá Ọjó sọ kéyìn lálẹ́ ọjọ́ náà tí ọlọ́jọ́ dé, tí ó sì mú un lọ. Àkókò wo ni ọ̀nkọ̀wé fihàn pé ọ̀rọ̀ yìí wáyé?

  • A. Àájìn
  • B. Àárọ̀ kùtùCorrect
  • C. Ìrọ̀lẹ́
  • D. Òrugànjọ́

Explanation

Bàbá Ọjó spoke 'láàárọ̀ kùtù' (very early morning).

Yoruba Language 2025 Objective — Question 7

Kí ni ọ̀nkọ̀wé ní ó le mú ènìyàn pegedé nílé ayé?

  • A. Èké ṣíṣe
  • B. Ìmélé ṣíṣe
  • C. Iṣẹ́ ṣíṣe
  • D. Olè jíjà

Explanation

He advised telling the truth (òtítọ́) as what makes a person great.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 9

Pàtàkì ohun tí bàbá Ọjó ń pe àkíyèsí ọmọ rẹ̀ sí ni láti jẹ́

  • A. alágbára
  • B. elékèé
  • C. olóòótọ́Correct
  • D. onírèéra

Explanation

His main advice is to be truthful (olóòótọ́).

Yoruba Language 2025 Objective — Question 10

Léyìn tí bàbá Ọjó parí gbogbo ìmọ̀ràn rẹ̀ ni ó

  • A. dágbére fáyéCorrect
  • B. jẹ tétè orí ire
  • C. kọjá lọ ìlú ọba
  • D. rẹ́jú díẹ̀

Explanation

After the advice he died that night, i.e. bade the world farewell.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 11

Èwo nínú àwọn àkọlé yìí ni ó jẹ́ mọ́ àròkọ ìṣípayá?

  • A. Aṣọ Ẹbi
  • B. Ìfẹ́ Di Aya Bánkọ́lé
  • C. Ilé Ọba Tí Ó Jó
  • D. Lẹ́tà Sí Ọ̀rẹ́ Mi

Explanation

Ìṣípayá (expository/descriptive account) fits describing a festival such as 'Ọdún Ifá Kan'.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 12

“Oko Bàbá Mi” jẹ́ àròkọ

  • A. alárìíyànjiyàn
  • B. aṣàpèjúweCorrect
  • C. asọ̀tàn
  • D. ìṣípayá

Explanation

Describing a place (father's farm) is a descriptive essay (aṣàpèjúwe).

Yoruba Language 2025 Objective — Question 13

“Ṣé dáadáa ni màmá mi wà” le jẹyọ nínú àròkọ

  • A. aṣàpèjúwe
  • B. asọ̀tàn
  • C. onílétà àìgbẹ̀fẹ́Correct
  • D. onílétà gbẹ̀fẹ́

Explanation

A friendly greeting like this appears in an informal letter (lẹ́tà àìgbẹ̀fẹ́).

Yoruba Language 2025 Objective — Question 14

“Ìlú Èkó Tí Mo Lọ” jẹ́ àròkọ

  • A. alárìíyànjiyàn
  • B. aṣàpèjúwe
  • C. asọ̀tànCorrect
  • D. ìṣípayá

Explanation

An account of a trip taken is a narrative essay (asọ̀tàn).

Yoruba Language 2025 Objective — Question 15

Àròkọ ____ kìí ní àkọlé.

  • A. aṣàpèjúwe
  • B. asọ̀tàn
  • C. lẹ́tà àìgbẹ̀fẹ́Correct
  • D. lẹ́tà gbẹ̀fẹ́

Explanation

An informal letter has no title; it begins with address, date and greeting.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 19

Níbo ni èémí tí a fi ń gbé ìró ìfọ̀ jáde ti ń wá?

  • A. Àfàsé
  • B. Ẹ̀dọ̀ fóróCorrect
  • C. Gògòǹgò
  • D. Ìfun

Explanation

Breath for speech comes from the lungs (ẹ̀dọ̀ fóró).

Yoruba Language 2025 Objective — Question 26

Àwọn obìnrin ìwòyí kò di irun mọ́, ‘àwọn’ nínú gbólóhùn yìí jẹ́ ọ̀rọ̀

  • A. àpèjúwe
  • B. arọ́pò afarajorúkọ
  • C. arọ́pò orúkọCorrect
  • D. atọ́kùn

Explanation

'Àwọn' is a (plural) pronoun-type word, arọ́pò orúkọ.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 27

Màá lọ ọjà tí mo bá jẹun tán. Èwo ni gbólóhùn àfarahẹ?

  • A. Bá jẹun tán
  • B. Jẹun tán
  • C. Lọ ọjà
  • D. Màá lọ ọjà

Explanation

The dependent (subordinate) clause is 'tí mo bá jẹun tán'.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 29

Olú sáré wo ọkọ̀ wá sílé. Gbólóhùn yìí jẹ́ àpẹẹrẹ gbólóhùn

  • A. alákànpọ̀
  • B. alátẹnumọ́
  • C. eléyọ ọ̀rọ̀ iṣẹ́
  • D. ìbéèrè

Explanation

The sentence has several verbs in a row (sáré, wo, wá): ọlọ́pọ̀ ọ̀rọ̀ iṣẹ́.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 30

A ṣẹ̀dá ____ nípa ṣíṣe àpètúnpè ọ̀rọ̀ orúkọ.

  • A. àrànmọ́
  • B. ìgbàgbọ́
  • C. ìlera
  • D. oníṣu

Explanation

ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀ is formed by repeating ọ̀sẹ̀.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 32

Bọ́ṣẹ lówó ṣùgbọ́n kò bímọ jẹ́ gbólóhùn

  • A. abọ́dé
  • B. alákànpọ̀Correct
  • C. àṣẹ
  • D. ìbéèrè

Explanation

Two clauses joined by 'ṣùgbọ́n' make a compound sentence (alákànpọ̀).

Yoruba Language 2025 Objective — Question 34

Dìran sun iṣu jẹ ní oko. Ọ̀rọ̀ iṣẹ́ ____ ni ó wà nínú gbólóhùn yìí.

  • A. aláìgbàbọ̀
  • B. aláìlẹ́ni
  • C. asolùwàdàbọ̀Correct
  • D. aṣokùnfà

Explanation

Two verbs follow the subject in a series (sun … jẹ), with a shared object.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 35

Ọmọ méjọ ni ó wà nínú ogbà náà, èyán aṣòǹkà inú gbólóhùn yìí ni

  • A. méjọCorrect
  • B. nínú
  • C. ogbà
  • D. ọmọ

Explanation

'Méjọ' (eight) is the numeral qualifier.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 36

Aṣọ yìí ti sá, ‘yìí’ tí ó wà nínú gbólóhùn yìí jẹ́

  • A. arọ́pò afarajorúkọ
  • B. arọ́pò orúkọ
  • C. atọ́kùn
  • D. èyánCorrect

Explanation

'Yìí' (this) qualifies the noun aṣọ: èyán.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 37

Olú ń tẹ̀lé jùwàjùwà, ‘jùwàjùwà’ inú gbólóhùn yìí jẹ́ ọ̀rọ̀

  • A. àpèjúweCorrect
  • B. àpọ́nlé
  • C. àsopọ̀
  • D. atọ́kùn

Explanation

'Jùwàjùwà' describes the manner of following: àpèjúwe.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 38

Aṣọ dúdú laṣọ ẹlẹ́wọ̀n, ‘dúdú’ jẹ́ ọ̀rọ̀

  • A. àpèjúweCorrect
  • B. àsopọ̀
  • C. atọ́kùn
  • D. iṣẹ́

Explanation

'Dúdú' (black) describes aṣọ: àpèjúwe.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 39

Agbọ̀n ni mo fi ru iṣu lọ sí ilé. Ọ̀rọ̀ iṣẹ́ tí ó wà nínú gbólóhùn yìí jẹ́

  • A. ẹyọ kan
  • B. méjìCorrect
  • C. mẹ́fà
  • D. mẹ́rin

Explanation

The verbs are 'ru' and 'lọ': two.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 41

Àìná lá ọbẹ̀ gbígbóná, ‘ọbẹ̀’ nínú gbólóhùn yìí jẹ́ ọ̀rọ̀

  • A. àpèjúwe
  • B. àpọ́nlé
  • C. atọ́kùn
  • D. iṣẹ́

Explanation

'Ọbẹ̀' (soup) is a noun.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 42

Èwo ni ó jẹ́ àpẹẹrẹ ibikan nínú ìwọ̀nyí?

  • A. Ewúrẹ́ àti ejò
  • B. Ẹyin àti ẹ̀wà
  • C. Igi àti owó
  • D. Kóredé àti Bísọ́lá

Explanation

Ọjà (market) and ilú (town) are places.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 44

Bóyè lọ aṣọ tí mo fọ̀. Olórí awẹ́ gbólóhùn ni

  • A. aṣọ tí mo fọ̀
  • B. Bóyè lọ
  • C. Bóyè lọ aṣọCorrect
  • D. lọ aṣọ

Explanation

The main clause is 'Bóyè lọ aṣọ'; 'tí mo fọ̀' is the dependent clause.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 47

Ìwọ pẹ̀lú Bọ́lá ni ẹ lọ, ‘pẹ̀lú’ nínú gbólóhùn yìí jẹ́ ọ̀rọ̀

  • A. àpọ́nlé
  • B. àsopọ̀Correct
  • C. atọ́kùn
  • D. iṣẹ́

Explanation

'Pẹ̀lú' (with/and) joins two nouns: àsopọ̀.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 48

Ọ̀rọ̀ tí ó ń ṣiṣẹ́ olùwà nínú gbólóhùn ni à ń pè ní ọ̀rọ̀

  • A. àpèjúwe
  • B. àpọ́nlé
  • C. atọ́kùn
  • D. iṣẹ́

Explanation

The subject of a sentence is a noun (ọ̀rọ̀ orúkọ).

Yoruba Language 2025 Objective — Question 49

Ó gbé owó náà pamọ́ sí abẹ́ ẹní. Ọ̀rọ̀ atọ́kùn nínú gbólóhùn yìí ni

  • A. abẹ́
  • B. ẹní
  • C. gbé
  • D. síCorrect

Explanation

'Sí' (to/in) is the preposition (atọ́kùn).

Yoruba Language 2025 Objective — Question 51

Èwo ni ó bá àkọtọ́ Yorùbá òde òní mu nínú àwọn wọ̀nyí?

  • A. Ọlọ́sàCorrect
  • B. Ọlọọsa
  • C. Ọlọsaa
  • D. Ọlọọṣà

Explanation

Choice A is the form that follows modern orthography among the options.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 52

Ìjẹ̀shà yóò di ____ nínú àkọtọ́ Yorùbá òde òní.

  • A. Ìjẹshà
  • B. Ìj ẹshà
  • C. Ìjẹ shà
  • D. Ìjẹ̀ṣàCorrect

Explanation

'sh' becomes 'ṣ' in modern orthography: Ìjẹ̀ṣà.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 53

Ọkan nínú àwọn wọ̀nyí ni ó bá ìlànà àkọtọ́ mu.

  • A. Ńbò
  • B. Ń bòCorrect
  • C. Ńbò ò
  • D. Ńbòò

Explanation

'Ń' is written apart from the verb that follows: Ń bọ̀.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 54

Nínú àkọtọ́ ọdẹ òní, bí a ti ń kọ ‘bótilẹ̀wùkórí’ nìyí

  • A. biotilewukori
  • B. bí ó tilè wù kóríCorrect
  • C. bíó tilè wù kórí
  • D. bí ó tilèwù kórí

Explanation

Modern orthography separates the words: bí ó tilẹ̀ wù kórí.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 55

Èwo ni ó bá àkọtọ́ ọdẹ òní mu nínú àwọn wọ̀nyí?

  • A. Nítorí ná
  • B. Nítoríínà
  • C. Nitorinaa
  • D. Nítorí náàCorrect

Explanation

Correct modern spelling is 'Nítorí náà'.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 61

Ọmọ mélòó ni Lámúrúdù bí?

  • A. Ẹyọkan
  • B. Méje
  • C. Méjì
  • D. Mẹ́rin

Explanation

Lámúrúdù is recorded in Yoruba history as the father of three notable children (Ọ̀dọ̀dúwà and his brothers).

Yoruba Language 2025 Objective — Question 67

Ọdún tí John Raban ṣe ìtẹ̀bọmi fún Bísọ́ọ̀bù Àjàyí Crowther, tí ó sì sọ ọ́ ní orúkọ ìgbàgbọ́ ni

  • A. 1815
  • B. 1820
  • C. 1825Correct
  • D. 1830

Explanation

Crowther was baptised in 1825.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 69

Ọdún wo ni Crowther jẹ oyè Bísọ́ọ̀bù?

  • A. 1802
  • B. 1844
  • C. 1852
  • D. 1856

Explanation

Best match among the options for his consecration as bishop (the exact year, 1864, is not printed).

Yoruba Language 2025 Objective — Question 70

Gbogbo àwọn wọ̀nyí ló kó ipa takuntakun lórí ìlànà kíkọ̀wé lédè Yorùbá àyàfi

  • A. Avezac
  • B. Carl lepsius
  • C. Crowther
  • D. Ìjọ Àgùdà

Explanation

Avezac, Lepsius, Crowther and the Catholic mission all shaped Yoruba writing; the Ìjọ Eléto did not.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 73

Èwo nínú àwọn oúnjẹ wọ̀nyí ni ó gbajúmọ̀ láàrin àwọn Ọ̀yọ́?

  • A. ÀmàlàCorrect
  • B. Ẹ̀wà
  • C. Ìkọ́kọ́ré
  • D. Iyán

Explanation

Àmàlà is the best-known Ọ̀yọ́ food.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 74

Ọkan nínú àwọn ìran wọ̀nyí ni a gbà pé ó jẹ́ ìran Yorùbá.

  • A. Ẹ̀gánCorrect
  • B. Fúlání
  • C. Haúsá
  • D. Íbò

Explanation

Ẹ̀gún/Ẹ̀gán is counted among Yoruba peoples; the rest are other ethnic groups.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 76

Èwo nínú àwọn ewì alohùn wọ̀nyí ni ó jẹ́ mọ́ àṣeyẹ?

  • A. Iwì egúngúnCorrect
  • B. Ìyẹ̀rẹ̀ ifá
  • C. Ògún pípè
  • D. Orin obitun

Explanation

Iwì is chanted at the egúngún festival.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 77

Dadakúàdá jẹ́ ewì àtinúdá fún ọkan nínú àwọn ẹ̀yà Yorùbá wọ̀nyí.

  • A. Ifẹ̀
  • B. Ìgbómìnà
  • C. Ìjẹ̀búCorrect
  • D. Oǹdó

Explanation

Dadakúàdá is associated with the Ìjẹ̀bú.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 78

Èwo nínú àwọn wọ̀nyí ló jẹ́ mọ́ ewì ajemẹ̀sìn?

  • A. Bọ̀lọ̀jọ̀
  • B. Dadakúàdà
  • C. Ègè dídá
  • D. Ògún pípèCorrect

Explanation

Ògún pípè (invoking Ògún) is religious oral poetry.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 80

Àárín àwọn ẹ̀yà Yorùbá wo ni ẹkún ìyàwó ti gbajúmọ̀ jùlọ?

  • A. Èkìtì
  • B. Ẹ̀gbá
  • C. Ìbàràpá
  • D. Ìgbómìnà

Explanation

Ẹkún ìyàwó (bridal chant) is best known among the Ọ̀yọ́.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 86

Èwo nínú àwọn wọ̀nyí ni ó jẹ́ orúkọ àmútọ̀runwá?

  • A. Abíọ́lá
  • B. Ayọ̀mídé
  • C. Babájídé
  • D. ÌdòwúCorrect

Explanation

Ìdòwú (child born after twins) is a name brought from heaven (àmútọ̀runwá).

Yoruba Language 2025 Objective — Question 88

Orúkọ wo ni Yorùbá ń pe adìyẹ tí wọ́n ń tú ìyẹ́ rẹ̀ níwájú òkú? Adìyẹ

  • A. gàgàrà
  • B. ìpèsè
  • C. ìrànàCorrect
  • D. òkú

Explanation

The chicken used in funeral rites is called adìyẹ ìrànà.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 89

Méjì nínú àwọn ohun èlò ìsọmọlórúkọ nílẹ̀ Yorùbá ni

  • A. àádùn àti ìrèké
  • B. aṣọ àti bàtà
  • C. ẹja àti ẹ̀gúsí
  • D. iyán àti ẹ̀gúsí

Explanation

Water (omi) and palm wine (ẹmu) are among the items used in naming ceremonies.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 90

Èwo nínú àwọn wọ̀nyí ni ó jẹ́ orísìí aṣọ Yorùbá kan?

  • A. AgbádáCorrect
  • B. Búláòsì
  • C. Jákẹ́ẹ̀tì
  • D. Kóòtù

Explanation

Agbádá is a traditional Yoruba garment; the others are Western.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 94

Èwo nínú àwọn wọ̀nyí ni kìí ṣe orúkọ àbíkú?

  • A. ÀìnáCorrect
  • B. Ajá
  • C. Dúrójayé
  • D. Dúrósinmí

Explanation

Ajá, Dúrójayé, Dúrósinmí and Málọmọ́ are àbíkú names; Àìná is not.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 95

Ètò tí ó kàn lẹ́yìn ìwádìí nínú ètò ìgbéyàwó ni

  • A. alárinà
  • B. ìdáná
  • C. ìfojúsódé
  • D. ìpalẹ̀mọ́

Explanation

After investigation (ìwádìí) comes the formal request, ìtọrọ.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 96

Ọjọ́ ____ ni wọ́n dá fún àwọn ọmọ oyè méjèèjì láti padà wá gbọ́ ẹni tí ifá yàn sí ipò ọba.

  • A. kejeCorrect
  • B. kejì
  • C. kẹfà
  • D. kẹrin

Explanation

Set text: the princes were given the seventh day to return.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 97

Ará ìlú gbàgbọ́ pé ó yẹ kí wọn bèèrè ìtọ́sọ́nà lọ́wọ́ ____ kí wọn tó yan ọba tuntun.

  • A. Eléduà
  • B. Èṣù
  • C. IfáCorrect
  • D. Kábíyèsí

Explanation

They believed Ifá should be consulted before choosing a new king.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 98

Ta ni ẹni tí ó bá Àjọkẹ́ àti Àdìsá wí pẹ̀lú ìbínú?

  • A. Àdìó
  • B. AkíngbàlàCorrect
  • C. Akinlabí
  • D. Olátúnjí

Explanation

Best reading of the set text (Akíngbàlà).

Yoruba Language 2025 Objective — Question 99

Ẹni tí ó pèsè àgbo fún kábíyèsí ọba Oyèdépò ni

  • A. Adéṣẹwà
  • B. Awójídé
  • C. IfáṣeunCorrect
  • D. Ìyáàjẹ̀bú

Explanation

Ifáṣeun, the herbalist, prepared the medicine.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 100

Báwo ni Mosúnmọ́lá ṣe jẹ́ sí ọba Oyèdépò?

  • A. Ìyálóde ìlú
  • B. Ìyàwó ọ̀rẹ́ rẹ̀
  • C. Olorì àgbàCorrect
  • D. Olorì kékeré

Explanation

She was his senior wife (olorì àgbà).

Yoruba Language 2025 Objective — Question 103

Olóyè Kọ́lápọ̀ Dábírí àti ta ni àwọn amòòkùn-ṣìkà ṣe ikú pa lọ́jọ́ kan náà?

  • A. Bọ́lá
  • B. Bọ́lárìnwáCorrect
  • C. Fúnké
  • D. Súlè

Explanation

Best reading of the set text.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 105

Èwo ni kò sí nínú orúkọ àwọn ògá ọlọ́pàá tó bá Ajímẹ̀tọ́ ṣiṣẹ́ ìwádìí rẹ̀?

  • A. Babárímisá
  • B. Bádé Jagunmólú
  • C. Bánkọ́lé LànàCorrect
  • D. Fẹ́mi Ládèjì

Explanation

Best reading of the set text.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 108

Orúkọ ọmọ ẹgbẹ́ tí Fákẹ́yẹ gba owó ilé lọ́wọ́ rẹ̀ ni

  • A. Agbájélọlá
  • B. Ajíṣafẹ́
  • C. ArólóyèCorrect
  • D. Làtífù

Explanation

Best reading of the set text.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 110

Báwo ni alàgbà Àṣàfá ṣe jẹ́ sí Fọláṣadé?

  • A. Alábàáṣiṣẹ́ Ajénifújà.
  • B. Dókítà ẹbí wọn.
  • C. Ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ọkùnrin.
  • D. Ẹni tí ó kù ní bàbá fún-un.Correct

Explanation

Best reading of the set text.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 111

Èwo nínú gbólóhùn yìí ni kìí ṣe òótọ́ nípa Bàbá Awòràwò?

  • A. Àwọn aláwo àdúgbò dítẹ̀ mọ́ ọn.
  • B. Kò sí ẹni tí ó mọ ibi tí ó ti wá.
  • C. Ó fẹ́ràn obìnrin púpọ̀.Correct
  • D. Ó fẹ́ràn tọmọdé tàgbà.

Explanation

Best reading of the set text.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 117

Nínú ewì ‘Ṣé Wọn Ò Rí Mi’, akéwì pe ohun tá a ṣe níkọ̀kọ̀ tá à fẹ́ kéèyàn ó mọ̀ ní

  • A. nǹkan àṣírí
  • B. ohun burúkú
  • C. ohun ìbẹ̀rù
  • D. ọ̀rọ̀ aláriwoCorrect

Explanation

Best reading of the poem.

Yoruba Language 2025 Objective — Question 118

A lè lo imọ̀ fún ____ nínú ewì ‘Ọpẹ’.

  • A. afárá ṣíṣe
  • B. aṣọ ríró
  • C. ilé kíkọ́
  • D. iná dídá

Explanation

Palm products are used for soap making (ọṣẹ ṣíṣe).

Yoruba Language 2025 Objective — Question 119

Nínú ewì ‘Ahun’ akéwì dábàá pé kí a fi ____ ran aláìní lọ́wọ́.

  • A. àdúrà
  • B. aṣọ
  • C. iṣẹ́
  • D. omi

Explanation

The poet urges sharing food (oúnjẹ) with the needy.

Advertisement

Sign up free to unlock

  • Score tracking
  • Practice history
  • Saved questions
  • Progress dashboard
  • Personalized sessions
  • Weak-topic breakdown

…and/or go further with premium services and No Ads.