BECE Yoruba Language 2025 Objective — Question 6
Question 6 of 120 from the Basic Education Certificate Examination (Junior WAEC) (BECE) Yoruba Language 2025 Objective paper, with the correct answer and a full explanation.
Advertisement
ÀKÀYÉ KEJÌ “Gbọ́ ìwọ ọmọ mi, máa fi ọgbọ́n pamọ́ dáadáa, dì í sí ọwọ́ òsì rẹ má ṣe fi sí ọwọ́ ọ̀tún kí o má baà fi jẹun. Òdodo ọ̀rọ̀ nìyí, òtítọ́ ni kí o máa sọ”. Bàbá Ọjó ni ó pe ọmọ rẹ̀, Àkànjí, láàárọ̀ kùtù ọjọ́ Ajé láti bá a sọ̀rọ̀ lórí ohun kan tó le mú ènìyàn pegedé nílé ayé. Ó tẹ síwájú ó ní, “Máṣe purọ́ ní ọjọ́ ayé rẹ, òtítọ́ lágbára, agbára rẹ̀ dájú, èké kò ní gbòǹgbò, pẹ̀lẹ́bẹ ni èké máa ń gé elékèé, ó sì máa ń gba iyì lọ́wọ́ ẹni. Bẹ̀rù ikú, bẹ̀rù àárùn, ṣọ́ra fún obìnrin. Féràn ọmọdé àti àgbà, ní kúkúrú, féràn gbogbo ènìyàn ṣùgbọ́n kóríra èké.” Ọ̀rọ̀ yìí ni bàbá Ọjó sọ kéyìn lálẹ́ ọjọ́ náà tí ọlọ́jọ́ dé, tí ó sì mú un lọ. Àkókò wo ni ọ̀nkọ̀wé fihàn pé ọ̀rọ̀ yìí wáyé?
- A. Àájìn
- B. Àárọ̀ kùtùCorrect
- C. Ìrọ̀lẹ́
- D. Òrugànjọ́
Explanation
Bàbá Ọjó spoke 'láàárọ̀ kùtù' (very early morning).
Advertisement
Sign up free to unlock
- Score tracking
- Practice history
- Saved questions
- Progress dashboard
- Personalized sessions
- Weak-topic breakdown
…and/or go further with premium services and No Ads.