All 100 questions from the Junior Secondary Certificate Examination (JSCE) Yoruba Language 2022 Objective paper, with the correct answer and a full explanation for each. Free, no signup needed.
AKAYE
Ise ki i se ohun amusire bee ni iya ki i se ohun amu sawada. Yoruba gba pe ise m oogun ise ati pe a, kij muse je ki a tun mu ise je, opa gbooro tia si fle'ise jihna rere ni ise. Niiorinaabi eniyan baji ni owuro, o di dandan fun iru eni bee ki owa ise se.
Oniruuru ise ni o wa ni lie Yoruba, die ninu won ni ise agbe, aso hihun, aso rire, ode sise, ikoko mimo, ilu lilu, ise ona sise, ati oee lolo.
Aso hihun se pataki ni ile Yoruba o si je iseto gbayi pupo ti o si ni owo gegere lori, se aso ni a fi n bo asiri ara wa, ise take tabo ni ise aso hihun ni lie Yoruba.
Ise aso hihun wopo laarin awon ara ipinle Oyo paapaa ni agbegbe Osun, Iseyin, Saki, Ilorin, ati ilu Oyo gan-an. A tun le ri awon ahunso ni Ado-Ekiti, Akure ati ni ilu Abeokuta.
Awon ohun elo aso hihun po die, ninu won ni- biribiri okeeke, kokogun tabi gowu, okoagbon-in, akawuu, lyiso ikere-ese tabi itese. Omu, apasa ofi, okuuru ati bee bee lo.
Dahun gbogbo ibeere wonyi:- ibeere 1-5
Nmu'Aypka oke yii, Yoruba gbagbo pe
A. Ise ni oogun iseCorrect B. Ise sise ko so pe ki a lowo lowoC. Ise sise ko pon dandanD. Ise ko ni owoExplanation Based on the passage on weaving (Aso hihun).
Otito nip e ....
A. Okunrin nikan ni o maa n hun asoB. Obinrin ni o maa n hun asoC. Tokunrin tobinrin ni o maa hun asoCorrect D. Agbe nio ma hun asoExplanation Based on the passage on weaving (Aso hihun).
Meta ninu agbegbe ti a le ti n awon ahunso ni
A. Oyo Omu ati IlorinB. Gowu Oya ati IlasaC. Abeokuta, Agbonin ati IlorinD. Osun, Iseyin ati AbeokutaCorrect Explanation Based on the passage on weaving (Aso hihun).
Opa gbooro ti a fi n le ise jinna ni .............
A. IseCorrect B. IscC. AseD. IseExplanation Based on the passage on weaving (Aso hihun).
Ise to gbayi, to sin i owo gegere lori laye atijo ni ..........
A. Aso titaB. Aso reranC. Aso hihunCorrect D. Aso rireExplanation Based on the passage on weaving (Aso hihun).
AKAYE EWI
Mo gba ounje gbo, ohun nii gbemii ro
Bodnje, o si ninu okun Kankan o si fara
Ounje lore, awo.
Lyan lounje, oka loogun
Airi rara la n jeko
Kenu ma diie ni ti guguru
iyan lalaga lawujo ounje
Oka lo se igba keji funyan
Lojo ti iyan loree gbeyawo
Obe egusflaya iyan, efo ifro nimule re
Lojo Amala fe laya n ko?
Ewedu oun gbegin lo yan laayo
Akara laya A... u bamba
Moinmo ... lolufe eko rnimu
Dundu ... kere
O joba ni i...
Dodo na...
O joba ... to
Alagbara k... bajumo l'alubosa
Borokini o... legusi
Bi gbogb... o to.
Won o je p... t'omi bawo
Niton om... gbogbo won
Bio sf omi, ounje, o si
Omi, omi, ... ni igbe aye eda
Dahun awon ibeere to tele ewi oke yii: Ibeere 6 -10
Imule iyan nini wi oke yii ni ........
A. Obe gbegiriB. Efo EleguusiC. Ev eduD. Efo riroCorrect Explanation Based on the poem on food (Akaye Ewi).
Akasu ninu ewi yii tump si
A. Eko jijB. Eko mimuC. efo nroD. OkaCorrect Explanation Based on the poem on food (Akaye Ewi).
Ori oro ti o ye fun ewi yii ni ............
A. Iyan daraB. Ounje lore awoCorrect C. Paataki OunjeD. Iwulo ounjeExplanation Based on the poem on food (Akaye Ewi).
"Yan laayo" ninu ewi oke yi tumo si
A. Tako ohun kanB. Feran ohun kanCorrect C. Korir ohun kanD. Lodi si ohun kanExplanation Based on the poem on food (Akaye Ewi).
"Borokinni" ninu ewi yii tumo si ..............
A. Eniyan buruku lawujoB. Ika eniyan l'awujoC. Eniyan iyi lawujoCorrect D. Odale eniyan lawujoExplanation Based on the poem on food (Akaye Ewi).
Leta aigbefe ni leta ti a ko si?
A. 'Aare orile edeB. Obi eniC. Egbon Iya eniD. Ore eni atataCorrect Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
"ile eko mi" je apeere aroko?
A. AlalayeB. AsotanC. AsapejuweCorrect D. AlariyanjiyanExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ninu aroko ti a ti n ki gbogbo eni ti o wu wa ni
A. oniletaCorrect B. omroyinC. asotanD. alalayeExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ohuntiafin daaroko Onisorongbesi moyato si aroko miiran ni
A. ipinroB. aya joC. ewiD. itakurosoCorrect Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
'Afipe Akanrnole ni
A. aarinahonB. eyinpkeCorrect C. ete isaleD. oleleExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Iro Konsonanti (b) je
A. afejietepeCorrect B. afajapeC. afeyinpeD. aferigipeExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Gbogbo iro Konsonanti ede Yoruba je
A. MokandilogunB. MejidinlogunCorrect C. MetadinlogunD. MerindinlogunExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Meloo ni ami ohun ede Yoruba?
A. MefaB. Marun-unC. MerinD. MetaCorrect Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ewo ni faweeii eyin nfnu awon wbnyi?
Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Iro kii tele ara won ninu akosfie oro ninu ede Yoruba.
A. konsonantiCorrect B. faweeiiC. amiD. alifabeetiExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Iro faweeli ............ kii beer oro ninu ede Yoruba ajumolo
Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Faweeli ede Yoruba pin si ona
A. mokanlaB. meieC. mqtaD. mejiCorrect Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Silebu meloo ni o wa ninu oro yi "Olowojeunjeje"
A. MerinB. MefaCorrect C. MejeD. MejoExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Oro to ba ihun batani "F - KF - KF - KF" mu ni
A. OmoobaB. AdenleC. AgbalagbaCorrect D. ObinrinnExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Oro aropo afarajoruko jeyo ninu gbolohun yii
A. Oun ni oluko peCorrect B. E maa loC. Mo re buredi jeD. Tunde fo asoExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Baba ode mu emu vo bamubamu. Oro aponleinu gbolohun yii ni
A. yoB. bambamuCorrect C. mu emuD. odeExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Olu jeun amo koyo. Isori oro ti a fala si labe:
A. asopoB. orukoC. apejuewCorrect D. atokunExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
"Korensi" je oro tia ya wo inu ede Yoruba ................. nipase
A. esinB. okowoCorrect C. bseluD. asaExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
"Clu je eja b mo din". Eyan, awe - gbolohun asapejuwe inu gbolohun yii ni
A. eja ti mo dinCorrect B. oluC. time dinD. je ejaExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Dele ati iya re gun iyan je. Oro ise mu gbolohunyii ni...
A. Dele ati iyaB. iya ati iyanC. gun ati iyanD. gun ati jeCorrect Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Iya Boiu din akara elepo. Apola ise inu gbolohun yii ni
A. din akaja elepoCorrect B. akara elepoC. iya Boiu dinD. elepoExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ewo ninu awon oro yinni o ba akoto ode-ori mu?
A. NitorinaaCorrect B. NitonnaaExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ni Yoruba n pe...............................
A. 49B. 59Correct C. 69D. 79Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ni ilana akoto ede Yoruba ode om: Ewo ni oto?
A. OlokpaB. OlopaaC. OlopaCorrect D. OloppaExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Joke bought a beautiful dress' tumo si
A. Joke ra asoB. Joke ran aso to daraC. Joke ra aso to rewaCorrect D. Joke ta aso to wuyiExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
'It rains everyday tump si................
A. Ojo yoo rq ni ojumoB. Ojo yoo maa ro ni ojoojumoC. Ojo n roD. Ojo n ro ni ojoojumoCorrect Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
'I am eating corn' tumo si
A. Mo nje agbadoCorrect B. Mo n yin agbadoC. Mo n ya agbadoD. Mon ya n agbadoExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
'1000' ni Yoruba n pe ni
A. egberinB. 'eedegberinC. 'e'edegberunD. egb'erunCorrect Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Bawo ni a se seda ' omokomo ?
A. Omo-ko-omoCorrect B. Omo - kpomoC. moko-moD. Omo-k-omoExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Oko ayokele merin ni oga mi ra. Isori giramawo ni merin?
A. Eyan asapejuweB. Eyan ajorukoC. EyanasonkaCorrect D. Tyan asafihanExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Awon idile ti o maa n lu ilu ni a n pe ni
A. ayanCorrect B. onfraraC. onijbD. aluluExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Omo ti o ni ika owo meta ni a n pe
A. AjantalaB. KasimawoCorrect C. libviD. OiugbodiExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Orirun iran Yoruba ni
A. Ile-IfeCorrect B. Ilu-OyoC. Ilu-EkoD. Ilu IbadanExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Omo to wa ninu apo mgba ti iya re bii ni a n pe ni
A. OjoB. AjayiC. OkeCorrect D. IdogbeExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ojo ......... ni Yoruba n somokunrin loruko laye atijo
A. kasan-anB. kejoCorrect C. KejeD. KefaExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ewe ti a fi n joye nile Yoruba ni a n pe ni ...
A. eweakokoCorrect B. eweodanC. ewe gbodogiD. eweopeExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Pari owe yii - Akii bani gbele ..............
A. ki a ma jeun papoB. ki a ma mo iwa eniCorrect C. ki a ma jo sunD. ki a ma jo sere papoExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Pari owe yii - Owo eni ni a fi n ..........
A. tun aye eni seCorrect B. tun imura eni seC. tun iwa ara eni seD. tun ounje eni seExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
A kii mo on gun, mo on te, ki iyan ewura ma .......?
A. eni to ni isoro ni yoo mo ati yanju isoro naaB. eni to n sise yoo mo bi yoo se pari reCorrect C. eni to fe se ara reExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Pari owe yii - Adiye funfun ...........
A. o po ni ojaB. nio maa n ko daadaaC. ko mo ara re lagbaCorrect D. dagba juloExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
'Fi aake kori tumo si...
A. tun enu aake seB. ko jaleC. sa loD. fi aake ko orunCorrect Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Pari owe yii - Adiye funfun ...............
A. o po ni pjaB. nfo maa n ko daadaaC. lo dagba juloD. ko mo ara re lagbaCorrect Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Omobinrin ti o je akobi ninu ebi .....
A. AremoB. AkobiC. DaoduCorrect D. BeereExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
"Annpa ogun, oguna fowo jona ni Yoruba n ki .........
A. OdeB. AlagbedeCorrect C. AkopeD. AwakoExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Orisa ti Yoruba n kin i "o l'omi nile feje we" ni .........
A. OyaB. EsuC. OgunCorrect D. SangoExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ogidi Olu / Oni Kannga ajipon / O bomi osuru weda je oriki .........
A. AjayiB. DadaCorrect C. IgeD. IdowuExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ifa dida lati mo bi ojo iwaju omo tuntun yoo ti n ni ..........
A. akosejayeCorrect B. EsuC. ese ifaD. ifa didaExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Oruko abiku ni ..........
A. KolawoleB. KawojueCorrect C. KayodeD. KoredeExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Eyi kii se ise obinrin ni ile Yoruba
A. Epo siseB. AmokokoC. AkopeCorrect D. Eni hihunExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Idana je mo asa ........... ni ile Yoruba
A. igbeyawoCorrect B. isomolorukoC. oye jijeD. isinkuExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Toka si eyi ti a n fi isu je ninu awon ounje wonyi ......
A. Amala lafunB. Amala duduCorrect C. Amala egeD. fufuExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Aso egungun ni Yoruba la n pen i ...........
A. ekuCorrect B. banteC. oyalaD. yeriExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Dawo tele tumo si ..............
A. sun sileB. fi owo le leC. yagbeCorrect D. ju owo sileExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Eni ti o n se ohun to losi si iwa omoluabi ni awujo ni .....
A. AgbofinroB. AmofinC. AlukoroD. ArufinCorrect Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Onidiri ni Yoruba ki bayi............
A. Arinpa ni togunB. Oju gbooro oC. E ku owo lomiCorrect D. Amoye oExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Iwi kike tabi esa je mo orisa ..........
A. OyaB. EsuC. EgungunCorrect D. ObatalaExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Mimu ni ti olele ............ nit i obitun
A. kikoB. didaC. gbigbeCorrect D. sisunExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Awon eya Yoruba ti o ni orin apepe ni ............
A. EgbaB. OyoCorrect C. EkitiD. IjebuExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ewi alohun ajemesin ni............
A. DadakuadaB. BoijoC. IjalaCorrect D. BiripoExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ewo ni litireso alohun .............
A. Orin etiyeriCorrect B. Ere sisaC. Ijo jijoD. Okoto titaExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Alo ............. Ni o ma a n ni orin ninu
A. AsotanB. ApagbeCorrect C. ApamoD. OlorinExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Kinni ewo orisa Esu?
A. OmiCorrect B. EpoC. AadunD. AadunExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Okan lara awon ere idayara nile Yoruba ni .........
A. tentenCorrect B. ta lo wa ninu ogbaC. ludo titaD. ere booluExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ori ...... ni Oduduwa ro si nigba ti o ti orun wa lati te aye do.
A. oke oyeB. oke onigbinC. oke oraCorrect D. oke mogunExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Captain Butcham Smith je ........ ni gbogbo ile Afrika ti ijoba Geesi ti n sakoso nigba kan ninu iwe "Oba Adesoji Aderemi"
A. Akowe AgbaB. Adari ijobaC. Omowe agbaD. Gomina agbaCorrect Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Oba miiran to joye leyin "Oba Adesoji Aderemii" ni ......
A. Oba Ooni Arole OoduaB. Oba Ooni Olori - AyeC. Oba Okunade Sijuade Olubuse KejiCorrect D. Oorisa Oba Adeyeye Enitan OgunwusiExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
"A de Pariisi ni orile ede Faranse" Eni ti o soro yii ni .......
A. Eniitan Adeoti OkunolaCorrect B. Eniola AuduC. Bangbola OkunolaD. Bamisay OkunadeExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ijiya ti ole je Gbolahan koju lorun fun iwa ika to hu laye ni pe
A. O n gbaleB. banteC. O n pataD. O n gbe kangaCorrect Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Olu eda inu iwe Awolowo Akinkanju Asiwaju ni ...............
A. Jeremaya Obafemi Oyeniyi AwolowoCorrect B. Josaya obatunde Oyewole AwolowoC. Jonsinni ObalolaD. Josua Obawole Oyeniran AwolowoExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Olori ijoba ekun iwo oorun ile naijiria nigba kan ro ni ...
A. Awonuga ObatundeB. Awolowo ObafemiCorrect C. Akintola SamuelD. Alfred RewaneExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Okan pataki ninu eko ti tan inu iwe Awolowo Akinkanju Asiwaju ko wa ni ...............
A. Ki a maa ko egbe to wu wa nile ekoB. Ki a maa fi eko wa sereC. Kia a gbe aye wa bi o se wu waD. Ki a ni ipinnu rere nipa ojo iwuwaCorrect Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Oruko awon omobinrin meteeta Akinola bi ni ............... ati .............
A. Folagbade, Folasikemi ati FolaniwaB. Folasayo, Folakemi ati FolasadeC. Folakemi, Folakunmi ati FolabonD. Folasade, Folaranmi ati FolakemiCorrect Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
" Ki won saa ti bge aremo mi fun mi? Eni to so oro yii ninu iwe ere onitan "Gbogbo lomo ni ...............
A. AdebamiB. okinC. OlayiwolaD. AkinolaCorrect Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ise onimo ero ni ............... Akinola n se le n to Kekoo gboye ni yunifasit .
A. FolasadeB. bemiC. FolagbadeCorrect D. burunmExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ore Adedoja ati Bisola ni ...............
A. MoradeyoB. BosunmolaC. MobolajiCorrect D. MojisolaExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ilu ............... ni ogbeni Aduralebo fi maa n wa si Abule Temidire
A. Aramoko- EkitiCorrect B. Ayedu - EkitiC. Ifaki- EkitiD. Oye- EkitiExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ninu iweitan apileko ojo oru Salako ni ..................
A. Ore oko MosunmolaB. Okunrin ti Mosunmola n fe teleC. Egbon oko MosunmolaCorrect D. Ore egbon MosunmlaExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Adigun ojonsu ti a tun mo si ikamudu ninu iwe igbeyin omo Abiko ni ................
A. Kareem HasanB. Ibrahim SaheedC. Hassan IbraheemD. Ibrahim KareemCorrect Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Okan lara eko ti a ri ko ninu iwe igbyin omo Abiliko ni ....
A. Ki a maa a se ere, papa, daadaaB. Ki a tete ma a wa owoC. Ki a maa ta ojaD. Ki a ma a se darapo mo egbe okunkunCorrect Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Oju kii riran mo ni asko idnwo je oro enu ninu iwe igbeyin omo Abiko.
A. OlakunleB. MoriaC. DamilolaCorrect D. SadeExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ninu ewi" Asa Yoruba" ohun to se e ................ni asa
A. PolongoCorrect B. PolowoC. OlayiwolaD. AkinolaExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ninu ewi " afojudi" alafojudi ko mo ................ Eniyan
A. aponleCorrect B. itabukuC. ibawiD. ikoriraExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ninu ewi ki wura too dan Ebu tumo si ege isu ti a fe ......
A. dinB. taC. gbinCorrect D. seExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ninu ewi AGbe lo ni iriri igbeyin Omode alaigboran ma a n kun fun ...............
A. Itelorun ati ayoB. Abamo ati ekunCorrect C. Idunnu ati ayoD. Erin ati isogoExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ninu ewi Tete akewi so pe onitete yoo di ....... Ni igbeyin aye won.
A. OnisuuruB. onijibitiCorrect C. Oniwa ireleD. ore ara iluExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ninu ewi omo oko, omo to ...... ni omo oko.
A. Feran faajiB. eran ere sisC. Tepa moseCorrect D. n soleExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ninu ewi "Omo Yahoo" Omo Yahoo maa n pari aye re si ............... ati .............
A. Rira oko boginni ati kiko ile nlaB. Fife arewa obinrinC. Yiya were ati kiku ojijiCorrect D. Bibi omo repete ati ola jaburataExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ninu orin ewi "RERE O" Rere je omo ..........
A. To kose yanjuB. alaigboranC. niwa rereCorrect D. to je gbajumoExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ninu iwe "iyan" akewi pe iyan ni
A. Baba ounjeB. Oga ounjeC. Agba ounjeD. Oba ounjeCorrect Explanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Ninu iwe "Olodumare" akewi so pe Olodumare lo ye ti gbogbo eniyan ma a ............
A. Kole funCorrect B. maa fun ni owoExplanation Answer chosen from Yoruba language and literature knowledge.
Sign up free to unlock Score tracking Practice history Saved questions Progress dashboard Personalized sessions Weak-topic breakdown…and/or go further with premium services and No Ads .