JSCE Yoruba Language 2022 Objective — Question 1
Question 1 of 100 from the Junior Secondary Certificate Examination (JSCE) Yoruba Language 2022 Objective paper, with the correct answer and a full explanation.
Advertisement
AKAYE Ise ki i se ohun amusire bee ni iya ki i se ohun amu sawada. Yoruba gba pe ise m oogun ise ati pe a, kij muse je ki a tun mu ise je, opa gbooro tia si fle'ise jihna rere ni ise. Niiorinaabi eniyan baji ni owuro, o di dandan fun iru eni bee ki owa ise se. Oniruuru ise ni o wa ni lie Yoruba, die ninu won ni ise agbe, aso hihun, aso rire, ode sise, ikoko mimo, ilu lilu, ise ona sise, ati oee lolo. Aso hihun se pataki ni ile Yoruba o si je iseto gbayi pupo ti o si ni owo gegere lori, se aso ni a fi n bo asiri ara wa, ise take tabo ni ise aso hihun ni lie Yoruba. Ise aso hihun wopo laarin awon ara ipinle Oyo paapaa ni agbegbe Osun, Iseyin, Saki, Ilorin, ati ilu Oyo gan-an. A tun le ri awon ahunso ni Ado-Ekiti, Akure ati ni ilu Abeokuta. Awon ohun elo aso hihun po die, ninu won ni- biribiri okeeke, kokogun tabi gowu, okoagbon-in, akawuu, lyiso ikere-ese tabi itese. Omu, apasa ofi, okuuru ati bee bee lo. Dahun gbogbo ibeere wonyi:- ibeere 1-5 Nmu'Aypka oke yii, Yoruba gbagbo pe
- A. Ise ni oogun iseCorrect
- B. Ise sise ko so pe ki a lowo lowo
- C. Ise sise ko pon dandan
- D. Ise ko ni owo
Explanation
Based on the passage on weaving (Aso hihun).
Advertisement
Sign up free to unlock
- Score tracking
- Practice history
- Saved questions
- Progress dashboard
- Personalized sessions
- Weak-topic breakdown
…and/or go further with premium services and No Ads.