Free account: track your progress — Sign up free

JSCE Yoruba Language 2023 Objective — Question 46

Question 46 of 100 from the Junior Secondary Certificate Examination (JSCE) Yoruba Language 2023 Objective paper, with the correct answer and a full explanation.

Advertisement

Báwo ni a ṣe ń kọ "Peter" tí a yá wọ inú èdè Yorùbá ní ọ̀nà afojúyá?

  • A. PétérùCorrect
  • B. Pétèr
  • C. Pétèrs
  • D. Pítèr

Explanation

Afojúyá: a yá ọ̀rọ̀ náà láti inú bí a ṣe kọ ọ́; Pétérù ni a fi ń kọ ọ́ nínú Bíbélì Yorùbá.

Advertisement

Sign up free to unlock

  • Score tracking
  • Practice history
  • Saved questions
  • Progress dashboard
  • Personalized sessions
  • Weak-topic breakdown

…and/or go further with premium services and No Ads.