JSCE Yoruba Language 2024 Objective — Question 1
Question 1 of 100 from the Junior Secondary Certificate Examination (JSCE) Yoruba Language 2024 Objective paper, with the correct answer and a full explanation.
Advertisement
Akáyé Ọlọ́rọ̀ Geere. Ìlú lẹ̀, kò sí owó lóde ni igbe àti orin tí àwọn ọmọ ìlú Ajéwọlé ń kọ. Àwọn onímọ̀ nípa ètò ọ̀rọ̀ ajé fi ọ̀nkọ̀rí, fi ìkùnlukùn láti mọ àwọn ohun tó ṣe okùnfà bí ọ̀rọ̀ ajé ìlú wọn ṣe ń ṣòjòjò. Nínú ìwádìí wọn ni wọ́n ti rí pé, ìlú Ajéwọlé kò ní ètò ọ̀rọ̀ ajé kan gúnmọ́ tí ó lè máa mú owó ìlú òkèèrè wọlé wá. Ìba ọ̀rọ̀ díẹ̀ tí wọ́n tún ní, wọ́n tún kó o lọ sí òkè òkun láti rajà lọ́wọ́ àwọn òyìnbó. Abájáde ìwádìí wọn láti lè ṣiṣẹ́ àti òṣì wọgbó nílùú, ni pé wọ́n fún àwọn ọmọ ìlú Ajéwọlé ní ìmọ̀ràn láti bẹ̀rẹ̀ sí ṣíṣe iṣẹ́ àgbè, kí oúnjẹ lè pọ̀ yanturu ní ìlú wọn. Lẹ́yìn èyí àwọn aráàlú yóò ní àǹfààní láti lè ṣe ìdókòwò pẹ̀lú àwọn òyìnbó, tí owó òkè òkun náà yóò sì máa wọ ìlú Ajéwọlé wá. Ìdàgbàsókè ńlá ni yóò máa wọnú ìlú Ajéwọlé, ohun gbogbo yóò sì di ìrọ̀rùn fún gbogbo ọmọ àti aráàlú Ajéwọlé. Àwọn ará ìlú wo ló ń kígbe kò sí owó lóde?
- A. Ìlú AjéwọléCorrect
- B. Ìlú Ìmàdò
- C. Ìlú Kájọlà
- D. Ìlú Mábọláje
Explanation
The passage opens with the cry of the people of Ajéwọlé town.
Advertisement
Sign up free to unlock
- Score tracking
- Practice history
- Saved questions
- Progress dashboard
- Personalized sessions
- Weak-topic breakdown
…and/or go further with premium services and No Ads.