All 100 questions from the Junior Secondary Certificate Examination (JSCE) Yoruba Language 2024 Objective paper, with the correct answer and a full explanation for each. Free, no signup needed.
Akáyé Ọlọ́rọ̀ Geere. Ìlú lẹ̀, kò sí owó lóde ni igbe àti orin tí àwọn ọmọ ìlú Ajéwọlé ń kọ. Àwọn onímọ̀ nípa ètò ọ̀rọ̀ ajé fi ọ̀nkọ̀rí, fi ìkùnlukùn láti mọ àwọn ohun tó ṣe okùnfà bí ọ̀rọ̀ ajé ìlú wọn ṣe ń ṣòjòjò. Nínú ìwádìí wọn ni wọ́n ti rí pé, ìlú Ajéwọlé kò ní ètò ọ̀rọ̀ ajé kan gúnmọ́ tí ó lè máa mú owó ìlú òkèèrè wọlé wá. Ìba ọ̀rọ̀ díẹ̀ tí wọ́n tún ní, wọ́n tún kó o lọ sí òkè òkun láti rajà lọ́wọ́ àwọn òyìnbó. Abájáde ìwádìí wọn láti lè ṣiṣẹ́ àti òṣì wọgbó nílùú, ni pé wọ́n fún àwọn ọmọ ìlú Ajéwọlé ní ìmọ̀ràn láti bẹ̀rẹ̀ sí ṣíṣe iṣẹ́ àgbè, kí oúnjẹ lè pọ̀ yanturu ní ìlú wọn. Lẹ́yìn èyí àwọn aráàlú yóò ní àǹfààní láti lè ṣe ìdókòwò pẹ̀lú àwọn òyìnbó, tí owó òkè òkun náà yóò sì máa wọ ìlú Ajéwọlé wá. Ìdàgbàsókè ńlá ni yóò máa wọnú ìlú Ajéwọlé, ohun gbogbo yóò sì di ìrọ̀rùn fún gbogbo ọmọ àti aráàlú Ajéwọlé.
Àwọn ará ìlú wo ló ń kígbe kò sí owó lóde?
A. Ìlú AjéwọléCorrect B. Ìlú ÌmàdòC. Ìlú KájọlàD. Ìlú MábọlájeExplanation The passage opens with the cry of the people of Ajéwọlé town.
Àwọn wo ló gbìmọ̀ pọ̀ láti wá ojútùú sí ètò ọ̀rọ̀ ajé tó ń ṣòjòjò?
A. Àwọn olójàB. Àwọn onímọ̀ ètò ọ̀rọ̀ ajéCorrect C. Àwọn ọba àti ìjòyèD. Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́Explanation The passage says the experts in economic planning investigated the problem.
Sọ ìtumọ̀ ọ̀rọ̀ yìí: "ọ̀rọ̀ ajé ń ṣòjòjò"
A. Ọ̀rọ̀ ajé ìlú ń lọ déédéB. Àwọn olùdókòwò ń wo ìlú wáC. Ọ̀rọ̀ ajé kò lọ déédéCorrect D. Àwọn ìjọba ń pín oúnjẹ fún aráàlúExplanation Ṣòjòjò means that the economy is not going well.
Ìmọ̀ràn tí àwọn onímọ̀ nípa ètò ọ̀rọ̀ ajé gba àwọn aráàlú ni pé ......
A. kí àwọn àgbàlagbà má ṣiṣẹ́ mọ́B. kí wọ́n máa lọ ra ọjà ní òkè òkunC. kí wọ́n máa lọ ṣiṣẹ́ òyìnbóD. kí wọ́n máa lọ ṣiṣẹ́ àgbèCorrect Explanation They advised the people to take up farming.
Iṣẹ́ àgbè ṣíṣe yóò mú kí ...... pọ̀ yanturu ní àárín ìlú.
A. àìríṣẹ́B. ebiC. iyànD. oúnjẹCorrect Explanation Farming will make food plentiful in the town.
AKÀYÉ - EWÌ. Fi ọ̀rẹ́ ẹ̀ rẹ han mí, kí n sọ irú ẹni tí o jẹ́. Ẹgbẹ́kẹ́gbẹ́ máa ń bà ìwà rere jẹ́, akẹ́kọ̀ọ́ tí kò fetí sẹ́kọ̀ọ́ tí òbí àti olùkọ́ ń kọ́ ọ, a máa kó àbámọ̀ níkẹyìn. Má bá àwọn mu oògùn olóró, kì í jẹ́ kọ́dọ̀ọ̀ ó bẹ́gbẹ́ pé. Asìlò oògùn olóró, ti mú ọpọlọ ọdọ́ di aláàgánná sí gbóró. Nígbà tí oògùn olóró bá ń peṣẹ̀ lára ọdọ́, ìwàkiwà ni 'rú u wọn ń hù láwùjọ. Ọmíràn lè forí lu ọpọ́ iná bí abujigè. Ẹ̀mí ọmọ ènìyàn kì í jọ wọ́n lójú mọ́. Bí wọ́n bá gbé kinní ọ̀hún lura tán, ìwà wèrè ló kù tí wọ́n ó máa hù. Akẹ́kọ̀ọ́ tó bá ń lo oògùn olóró, kò lè kẹ́kọ̀ọ́ yege. Gbogbo abiamọ àti olùkọ́, ẹ jẹ́ ká ṣowópọ̀. Ká gbógun ti ìwà ìbàjẹ́, kí aṣìlò oògùn olóró kúrò láwùjọ wa. Kí ilé ayé ó lè rójú, káwùjọ wa ó tòrò nínú. Kójọ̀ ọ̀la àwọn ọmọ wa ó lè dára.
Irú ẹgbẹ́ wo ni ó ń ba ìwà rere jẹ́? (Akáyé-Ewì: Fi ọ̀rẹ́ ẹ̀ rẹ han mí, kí n sọ irú ẹni tí o jẹ́)
A. Ẹgbẹ́ onímọ̀B. Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́C. Ẹgbẹ́kẹ́gbẹ́Correct D. Ẹgbẹ́ Akẹ́kọ̀ọ́Explanation The poem warns about bad company, ẹgbẹ́kẹ́gbẹ́.
Ẹ̀kọ́ àwọn tó yẹ kí akẹ́kọ̀ọ́ ó fetí sí ni ......?
A. ẹ̀kọ́ àwọn (unreadable)Correct B. ẹ̀kọ́ (unreadable)C. ẹ̀kọ́ ẹgbẹ́kẹ́gbẹ́D. ẹ̀kọ́ àwọn olóògùn olóróExplanation Options A and B are blacked out in the scan. This is a guess.
Asìlò oògùn olóró ló máa ń mú kí ọpọlọ ọdọ di ......
A. aláàgánnáB. ọlọ́gbọ́nC. olópolo pípéCorrect D. aláìníṣẹ́Explanation Drug abuse damages the brain.
Akẹ́kọ̀ọ́ tó bá ń lo oògùn olóró kò lè ......
A. kẹ́kọ̀ọ́ yegeCorrect B. lọ sí ìlú òyìnbóC. jàD. bímọExplanation A drug user cannot pass his studies.
Àkọlé tó bá ewì yìí mu ni ......?
A. imọ̀ràn òbí àti olùkọ́B. ògùn olóróCorrect C. akẹ́kọ̀ọ́D. abiamọExplanation The poem is about the effects of drugs.
Fonọ́lọ́jì ni ẹ̀kọ́ nípa ......?
A. síláìbùB. kọ́ńsónántìC. àwọn ìró èdèCorrect D. ìsọ̀rí ọ̀rọ̀Explanation Phonology is the study of speech sounds.
Lẹ́tà tí a kọ sí Gíwá ilé ẹ̀kọ́ wa láti fi ẹ̀hónú hàn ni ......?
A. lẹ́tà ẹ̀hónúCorrect B. lẹ́tà ìfẹ́C. lẹ́tà gbẹ́fẹ́D. lẹ́tà àìgbẹ́fẹ́Explanation A letter of complaint is a lẹ́tà ẹ̀hónú.
Lẹ́tà tí a máa ń bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú "Bàbá mi tòótọ́" jẹ́ ......?
A. lẹ́tà aìgbẹ́fẹ́B. lẹ́tà àìgbẹ́fẹ́ àti gbẹ́fẹ́C. lẹ́tà tí a kọ sí ọgá ẹniD. lẹ́tà gbẹ́fẹ́Correct Explanation A letter that begins like this is an informal letter (gbẹ́fẹ́).
"Lílo ẹ̀rọ ìgbàlódé kó àwọn akẹ́kọ̀ọ́ sàn ju lílo ojú pátákó àti efun ìkọ̀wé lọ" jẹ́ ......?
A. àròkọ alálàyéB. àròkọ onísọ̀rọ̀ngbèsìCorrect C. àròkọ alárinyànjiyànD. àròkọ asotànExplanation Arguing for one position over another is an argumentative essay.
Ọdún Èdè àti Àṣà Yorùbá tí a ṣe ní ilé ẹ̀kọ́ mi jẹ́ àpẹẹrẹ ......
A. àròkọ AṣapèjúweCorrect B. àròkọ AsotànC. àròkọ AlárinyànjiyànD. àròkọ AlálàyéExplanation Describing an event is a descriptive essay (aṣapèjúwe).
Àpẹẹrẹ orí ọ̀rọ̀ tó jẹmọ́ Àròkọ Alálàyé ni èyí ......
A. iṣẹ́ ìlú lílùCorrect B. bí mo ṣe lo ìsinmi mi tó kọjáC. ìgbà òjò dáraD. eré ìdíje onílé ìjílé tí a ṣe nílé ẹ̀kọ́ miExplanation An expository topic explains a process. This is a guess.
Ẹ̀wọ̀ nínú àwọn kókó wọ̀nyí ni kò wúlò nínú àròkọ kíkọ ní èdè Yorùbá?
A. Àwòrán yíyàCorrect B. ÌfáàràC. Ìgúnlẹ̀D. Ìlapa èròExplanation Drawing pictures is not part of writing an essay.
Èwo ni fáwẹ́lì àìránmúpè nínú àwọn wọ̀nyí?
A. inB. eCorrect C. ẹnD. ọnExplanation E is an oral vowel; in, ẹn and ọn are nasal.
Kọ́ńsónántì àránmúpè aṣesílébù nínú àwọn wọ̀nyí ni ......
A. w àti bB. n àti unC. n àti mCorrect D. m àti inExplanation The syllabic nasal consonants are n and m.
Èwo ni èyà ara ìfọ̀ / ìpéró nínú àwọn wọ̀nyí?
A. Ọwọ́B. OjúC. Ẹsẹ̀D. ÈtèCorrect Explanation The lips (ètè) are an organ of speech.
Àwọn èyà ara ìfọ̀ / ìpéró tó dúró gbọn-in sí ojú kan tí a bá ń sọ̀rọ̀ ni ......
A. afipè àsúnsíB. afàṣẹC. èdòfóróD. afipè àkànmọ́lèCorrect Explanation Fixed articulators do not move; these are the afipè àkànmọ́lè.
Ìlànà tí a fi ṣẹ̀dá "Ọ̀gẹ̀dẹ̀" ni ......
A. KFFKFB. FFKKFC. FKFKFCorrect D. KFFKFExplanation Ọ-gẹ-dẹ is a vowel, consonant, vowel, consonant, vowel pattern: FKFKF.
Ọ̀rọ̀ tí a ṣẹ̀dá pẹ̀lú KFKFKF ni ......
A. ọ̀gẹ̀dẹ̀B. fáwẹ́lìCorrect C. babanláD. alayéExplanation Fa-wé-lì is K-F-K-F-K-F.
Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a ṣẹ̀dá nípa ṣíṣe àpètúnpè àpọ́lá-iṣẹ́ ni ......
A. pẹ́jápẹ́jàCorrect B. ọmọọmọC. ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀D. ọdọọdúnExplanation Pẹ́jápẹ́jà comes from reduplicating a verb phrase. This is a guess.
Ayélabọ́lá jẹ́ ọ̀rọ̀ oníṣílébù mélòó?
A. Márùn-únCorrect B. Mẹ́rinC. Mẹ́fàD. Mẹ́taExplanation A-yé-la-bọ́-lá has five syllables.
Pín ọ̀rọ̀ yìí sí síláìbù "Aláńtakùn".
A. A-lá-nta-kunB. A-lá-n-ta-kunCorrect C. A-lán-ta-kunD. A-lá-n-ta-ku-nExplanation The syllabic nasal n forms its own syllable.
Èwo ni kì í ṣe ìsọ̀rí ọ̀rọ̀ inú èdè Yorùbá nínú àwọn wọ̀nyí?
A. Ọ̀rọ̀-iṣẹ́B. Ọ̀rọ̀-atọ́kùnC. Iṣẹ́dá-ọ̀rọ̀Correct D. Ọ̀rọ̀-orúkọExplanation Word formation is a process, not a word class.
Fi àmì ohùn sí orí ọ̀rọ̀ yìí "Akoko" (Time)
A. AkokoB. AkòkóC. ÀkòkòD. ÀkókòCorrect Explanation The word for time is àkókò.
Àpẹẹrẹ ọ̀rọ̀ arọ́pò afarajorúkọ ẹyọ ni ......
A. awaB. àwọnC. èyinD. ounCorrect Explanation Oun is a singular pronoun; the others are plural.
"Bàbá ọdẹ pa ẹyẹ". Àpólà orúkọ nínú gbólóhùn òkè yìí ni ......
A. pa ẹyẹB. ọdẹ pa ẹyẹC. bàbá ọdẹCorrect D. ọdẹ pa ẹyẹExplanation Bàbá ọdẹ (the hunter's father) is the noun phrase.
Mo jẹ èkọ (méjọ) ní àná. Ọ̀rọ̀ tó wà nínú àkámọ́ jẹ́ ......
A. èyán aṣafihànB. èyán aṣọnkàCorrect C. èyán aṣapèjúweD. èyán alálàyéExplanation Méjọ (eight) is a numeral qualifier, èyán aṣọnkà.
Ìsọ̀rí ọ̀rọ̀ tó máa ń fún gbólóhùn ní ìtumọ̀ ni ......
A. ọ̀rọ̀-iṣẹ́Correct B. ọ̀rọ̀-orúkọC. ọ̀rọ̀-arópò orúkọD. ọ̀rọ̀-atókùnExplanation The verb gives a sentence its meaning.
Gbólóhùn tó ní ẹyọ ọ̀rọ̀-iṣẹ́ kan ṣoṣo ni à ń pè ní ......
A. gbólóhùn abọ́déCorrect B. gbólóhùn ìbéèrèC. gbólóhùn alákànpọ̀D. gbólóhùn ọlọ́pọ̀ ọ̀rọ̀ iṣẹ́Explanation A sentence with a single verb is a simple sentence (abọ́dé).
Ìgbà wo ni ọ̀gá dé? Jẹ́ ......
A. gbólóhùn àlayéB. gbólóhùn ìbéèrèCorrect C. gbólóhùn ọlọ́pọ̀ ọ̀rọ̀ iṣẹ́D. gbólóhùn eléyọ ọ̀rọ̀ iṣẹ́Explanation It is a question, so an interrogative sentence.
Péjú se ọ̀gẹ̀dẹ̀ dúdú. "Dúdú" jẹ́ àpẹẹrẹ ìsọ̀rí ọ̀rọ̀ ......
A. ọ̀rọ̀ atọ́kùnB. ọ̀rọ̀ orúkọC. ọ̀rọ̀ àpèjúweCorrect D. ọ̀rọ̀ àpónléExplanation Dúdú (black) describes the plantain, so it is a descriptive word.
Inú gbólóhùn tí a ti lè rí àwẹ́ gbólóhùn ni ......
A. gbólóhùn eléyọ ọ̀rọ̀-iṣẹ́B. gbólóhùn àyísódìC. gbólóhùn alálàyéD. gbólóhùn oníbọ̀Correct Explanation A clause appears inside a complex sentence (oníbọ̀).
Bí mo ti dé ilé, mo jẹun. "Mo jẹun" jẹ́ ......?
A. awẹ́ gbólóhùn afarahẹ aṣàpónléB. awẹ́ gbólóhùn afarahẹ aṣodorúkọC. awẹ́ gbólóhùn afarahẹ aṣapèjúweD. olórí awẹ́ gbólóhùnCorrect Explanation Mo jẹun is the main clause.
Délé jókòó sí orí àga. Ọ̀rọ̀ atọ́kùn inú gbólóhùn yìí ni ......
A. DéléB. oríC. síCorrect D. jókòóExplanation Sí (on, to) is the preposition.
Èwo ni àkọtọ́ rẹ̀ kò tọ̀nà nínú ọ̀rọ̀ wọ̀nyí?
A. Pẹ̀tẹ́lẹ̀B. Pẹ́pẹ̀ìyeCorrect C. Pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́D. PápáánàExplanation The spelling pẹ́pẹ̀ìye looks wrong. This is a guess.
Àpẹẹrẹ èyà ara ìfọ̀ tí a kò lè foju rí ni ......
A. kòmóòkunCorrect B. ètèC. ẹnuD. àjà ẹnuExplanation The larynx is inside the body and cannot be seen.
Parí òwe yìí: "Ẹni tó yá egbàafà tí kò san ......"
A. ó bẹ́gi dínà egbèjeCorrect B. kò ní náwó tánC. yóò lówó tó pọ̀D. ó di dandan kó ní egbàáwàáExplanation The proverb continues with the debt growing. Best guess.
Kín ni ònkà Yorùbá fún 230?
A. ỌjìlérúgbaB. Ọjìlérúgba dín mẹ́wàáC. Ọjìlérúgba lé mẹ́wàáCorrect D. Ọjìlérúgba dín mẹ́fàExplanation Ọjìlérúgba is 220, so 230 is lé mẹ́wàá.
Okòólérúgba dín mẹ́wàá jẹ́ ......
A. 220B. 222C. 210Correct D. 230Explanation Okòólérúgba is 220; minus ten is 210.
Ònkà èdè Yorùbá fún 480 ni ......
A. òtàlé níríwóB. okòólé nírínwóC. ojilé nírínwóD. ọ̀rìnlé nírínwóCorrect Explanation 480 is 80 plus 400, ọ̀rìnlé nírínwó.
Túmọ̀ gbólóhùn èdè Gẹ̀ẹ́sì yìí sí èdè Yorùbá "Pride goes before destruction"
A. Ìgbéraga ní èrèB. Ìgbéraga jẹ́ àfojúdiC. Ìgbéraga máa ń boríD. Ìgbéraga ní ì sááju ìparunCorrect Explanation Pride comes before destruction, ìgbéraga ní ì sááju ìparun.
Ẹjìlé lọ́ọ́dúnrún jẹ́ ...... ní figò.
A. 402B. 202C. 302Correct D. 102Explanation Ẹjìlé lọ́ọ́dúnrún is 300 plus 2.
Ọjìlé lọ́ọ́dúnrún jẹ́ ......
A. 335B. 340Correct C. 345D. 350Explanation Best guess from the numeral pattern.
"Charity begins at home" túmọ̀ sí ......
A. ilé ni a tí ń kó ẹ̀sọ́ ròdeB. ifẹ́fúnni bẹ̀rẹ̀ láti iléCorrect C. ilé ni ẹ̀kọ́ wàD. ó dára láti láwọ̀Explanation Charity begins at home means kindness starts from the home.
"Our future will be great" túmọ̀ sí ......
A. ọjọ́ ọ̀la wa yóò dáraCorrect B. a ó gbádùn ní ọ̀laC. oní la mọ̀, a kò mọ ọ̀laD. ìgbádùn ni ti wa lójó ọ̀laExplanation Ọjọ́ ọ̀la wa yóò dára means our future will be good.
"A good student should try to break new ground" túmọ̀ sí ......
A. akẹ́kọ̀ọ́ gidi gbọ́dọ̀ kàwéB. akẹ́kọ̀ọ́ gidi gbọ́dọ̀ gbìyànjú láti ṣe ohun tuntunCorrect C. akẹ́kọ̀ọ́ gidi gbọ́dọ̀ lè lu ilẹ̀D. akẹ́kọ̀ọ́ gbọ́dọ̀ wá ọ̀rọ̀ inú iléExplanation Breaking new ground means trying new things.
"Our teacher tells us that cutting corners is not profitable" túmọ̀ sí ......
A. olùkọ́ wa sọ pé gbígbà kò dáraB. olùkọ́ wa sọ pé gígé igun kò dáraC. olùkọ́ wa sọ pé ọgbọ́n àrékérekè kò lérèCorrect D. olùkọ́ sọ fún wa pé ọgbọ́n wa kò lérèExplanation Cutting corners means using tricks, and tricks do not pay.
Ọmọ Ọkànbí tó jẹ́ obìnrin ni ......
A. AláàfinB. ỌṣẹmàwéCorrect C. AlákéD. OlówuTúnṣe àkọtọ́ òde-òní: "Taffa lọ offa"
A. Taffa lọ ọfaB. Tàfá lọ tafaC. Tàfá lọ ọ̀fàCorrect D. Táfá lọ ọ̀fàExplanation The modern spelling with tone marks is Tàfá lọ ọ̀fà. Best guess.
Ọ̀kúnfà ogun jíjà láyé àtijọ́ ni ......
A. ibáṣepọ̀ láàrin ìlú méjìB. pípẹtù sáàwọ̀ láàrin ìlú méjìC. ìjà àlà ilẹ̀Correct D. títúúkáExplanation Land boundary disputes were a common cause of wars.
Parí gbólóhùn yìí "aboyún bí, ara ......"
A. sófoB. tù úCorrect C. tútùD. wúwoExplanation Aboyún bí, ara tù ú: when a pregnant woman delivers she feels relief.
Igbésẹ̀ àkọ́kọ́ nínú àṣà ìgbéyàwó abínibí ilẹ̀ Yorùbá ni ......
A. ìtọ́jú àsọ̀déB. alárinàCorrect C. ibááléD. ìtọ́rọExplanation The alárinà (go-between) comes first in the traditional marriage.
Àdìá fún jẹ́yọ nínú ewì alohùn àjẹmọ́sìn ibílẹ̀ ......
A. ẹsẹ ifáCorrect B. ẹ̀sà egúngúnC. ọ̀fọ̀D. oríkì orílẹ̀Explanation Àdìá fún (they cast Ifá for) is found in Ifá verses (ẹsẹ Ifá).
Ọ̀kan lára ọ̀nà tí Yorùbá ń gbà ṣe ìtọ́jú aboyún láyé àtijọ́ ni ......
A. lílo oògùn òyìnbóB. jíjẹ asèje àti mímu àgbo oníruurúCorrect C. rírí dókítà oníṣègùn òyìnbóD. gbígba abẹ́rẹ́ àjẹsáraExplanation Pregnant women took local herbs and decoctions.
Ọ̀kan lára ọge ṣíṣe nílé Yorùbá láyé àtijọ́ ni ......
A. etè kíkùnB. irun jíjóC. làálì líléCorrect D. sòkòtò wíwọ̀ fún obìnrinExplanation Laali (henna) was a traditional adornment.
Báwo ni a ṣe ń kí akọpe?
A. Ìgbà á dá oB. Ojú gbooro oC. Ọwọ́ á yá oCorrect D. Ìgbà á rọ̀ oExplanation Best guess; the word akọpe is not clear in the scan.
Àṣà ìranra ẹni lọ́wọ́ tó jẹ́ iṣẹ́ ìlú ni ......
A. arokodókoB. owẹ̀Correct C. owó ẹléD. ẹ̀bẹṣẹExplanation Owè is a traditional mutual-help work group.
Babaláwo la ń kí pé ......
A. abọ́yè bọ sísẹ́B. kí ifá ó gbà oC. ifá á ṣe oD. abọ́rúbọyè oCorrect Explanation Best guess; babalawo is greeted as abọ́rúbọyè.
Ọ̀kan lára iṣẹ́ abínibí ilẹ̀ Yorùbá ni ......
A. iṣẹ́ Ọlọ́pàáB. iṣẹ́ Agbẹ̀dẹCorrect C. iṣẹ́ TísàD. iṣẹ́ Wọlẹ́wọlẹ́Explanation Blacksmithing (agbẹ̀dẹ) is a traditional Yoruba occupation.
Ìtún lọ́ ni kí ẹ tún mi ṣe, Ifà ló ni kí ẹ fà mí mọ́ra, Abèèrè ló ní kí ẹ fi rẹ gbogbo bèèrè mi. Irúfẹ́ ewì alohùn wo nìyí?
A. Ọfọ̀Correct B. Oríkì orílẹ̀C. Ẹ̀sà egúngúnD. Ìyẹ̀rẹ̀ ifáExplanation An incantation is called ọfọ̀.
Ẹni tó ti kú ni Yorùbá ń pè ní ......
A. olóògbéCorrect B. ológbéC. ológbeD. ológbèéExplanation The deceased is called olóògbé.
Èwo ni orúkọ àbíkú nínú àwọn orúkọ wọ̀nyí?
A. ÀìnáB. DáìísìC. DáòdùCorrect D. ÀlàgbéExplanation Best guess; the names are partly unclear in the scan.
Lára ojúṣe ọmọlúàbí ni ......
A. kì í kẹ́kọ̀ọ́B. kì í jíṣẹ́ fún àgbàlagbàC. kí ó ní ìteríba fún àgbàCorrect D. kì í wá sí ilé ẹ̀kọ́ déédéExplanation A well-mannered child respects elders.
Èwo ni kì í ṣe oríkì obìnrin?
A. Àyìnkẹ́B. Adùkẹ́C. Àsàkẹ́D. Àmọ̀óCorrect Explanation Best guess; the other three are girls' pet names.
Ilà kíkọ tí a fà láti agbárí wá sí èrèkè ni Yorùbá ń pè ní ......
A. péléB. abàjàCorrect C. kẹ́kẹ́D. gòmbóExplanation Abàjà are the tribal marks from the temple to the cheek.
Orúkọ tó jẹmọ́ ìran onísàngó ni ......
A. Ọjẹ́dìranB. KúmápayíC. BámgbóṣéCorrect D. AníbisálàExplanation Bámgbóṣé contains Ṣàngó (ṣé).
Èṣù léyìn Adéoyè tí ó kóbá a tí omi ọbẹ̀ rẹ̀ fi dànù nínú ìwé "OMI ỌBẸ̀ DÀNÙ" ni ......
A. ÀdùnníB. OlúbísíCorrect C. Àdùkẹ́D. AdélájàExplanation Set-text question; I have not seen the book. This is a guess.
Ẹni tí ó tú àṣírí oògùn ìkà tí Adéoyè lọ ṣe lọ́dọ̀ Awódáre láti ya Mátànmí ní wèrè ni ......
A. IfáṣínàCorrect B. AwódáreC. OlúṣèyẹD. Ọ̀gá Ọlọ́pàáExplanation Set-text question; this is a guess.
Orúkọ ilé-iṣẹ́ búrẹ́dì tí Mátànmí àti Adéoyè jẹ́ aláṣẹ àti olùdarí ni ......
A. Ọ̀rẹ́dọláCorrect B. Ọ̀rẹ́dùnníC. Ìwájọ̀wàD. Ọ̀rẹ́ṣoroExplanation Set-text question; this is a guess.
Ní ọdún ...... ni a kọ́kọ́ ṣe ọdún ẹyọ fún ọba Akíntóyè ní ìlú Èkó.
A. 1894B. 1854Correct C. 1998D. 1966Explanation Set-text (history) question; this is a guess.
Ẹni tó gbà pé ìtànjẹ ọ̀rọ̀ gbáà ni tí akẹ́kọ̀ọ́ kan bá sọ pé "SCHOOL IS A SCAM" ni ......
A. KéjìCorrect B. ÀkeemC. TúnjíD. ÌdòwúExplanation Set-text question; this is a guess.
Iṣẹ́ tí "ÀWỌN ỌRẸ́ MẸ́FÀ" ń ṣe ni ......
A. iṣẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọB. iṣẹ́ onímọ̀ ìṣiròC. iṣẹ́ olùkọ́D. iṣẹ́ yahùú pílọ̀ọ̀sì àti títa oògùn olóróCorrect Explanation Set-text question; this is a guess.
Fíjàbí tó jẹ́ olórí ẹgbẹ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ rọ gbogbo akẹ́kọ̀ọ́ pé ......
A. kí àwọn darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òkùnkùnCorrect B. kí àwọn máa dáwọ́ fún ẹgbẹ́ òkùnkùnC. kí àwọn máa ṣayẹ̀ṣí ẹgbẹ́ òkùnkùnD. kí àwọn gbógun ti àwọn ẹgbẹ́ òkùnkùnExplanation Set-text question; this is a guess.
Ìgbà mélòó ni Ayọ̀bámi fídí rẹ̀mi nínú ìdánwò Wáẹ̀kì tó ṣe?
A. Ìgbà méjìB. Ìgbà mẹ́taCorrect C. Ìgbà mẹ́rinD. Ẹ̀ẹ̀kan ṣoṣoExplanation Set-text question; this is a guess.
Nínú ìwé Lítírẹ́sọ̀ Àpilẹ̀kọ "Ayédèrú" Ta ni ó fún Tínú lóyún tí kò gba oyún náà?
A. JíbówúCorrect B. Ayọ̀bámiC. Tọ́yèD. DáreExplanation Set-text question; this is a guess.
Ta ni ẹni tí ó sọ gbólóhùn yìí "ní báyìí Ìjì ti gbé e mi" nínú ìwé Ìjì?
A. Mónìjà DonaldB. BísíC. WọléCorrect D. DéọláExplanation Set-text question; this is a guess.
Nínú ìwé Ìjì, ẹni tí àwọn òyìnbó mú lọ sí ìlú òyìnbó láti máa gbá bọ́ọ̀lù nínú àwọn ọmọ Ṣadé ni ......
A. MàlikB. FareedCorrect C. FareedahD. Táyé àti Kẹ́hìndéExplanation Set-text question; this is a guess.
Ìwà ...... kò sí nínú ìwà ọmọlúàbí nínú ìran Yorùbá?
A. ìranra ẹni lọ́wọ́B. ìfipábánilòpọ̀Correct C. ìbọ̀wọ̀fúnniD. iṣàpónléExplanation Forced sex is not part of good Yoruba conduct.
Ẹ̀kọ́ pàtàkì kan tí ìwé Tèmilọ́tán kọ́ wa ni pé ......
A. iṣẹ́ ibi ló dára ká máa ṣeB. ìwà àìkàn̄jopọ́n ló yẹ ká máa hùC. iṣẹ́ ibi àti ìwà ìkà kò dára láwùjọCorrect D. ìwà ọmọlúàbí kò dára láwùjọExplanation Bad deeds and wickedness are not good for society.
Ta ni olóṣèlú tí ó fẹ́ du ipò Gómìnà ìlú rẹ̀ nínú ìwé Tèmilọ́tán?
A. OyèrìndéB. OritóókèCorrect C. Fèyísayọ̀D. Ọgbọ́nmípọ̀Explanation Set-text question; this is a guess.
Kí ni ó mú kí ọkọ Eniọpẹ́tọ́sí kò ó sílẹ̀?
A. Nítorí pé ó jẹ́ onífwààlà obìnrinB. Nítorí pé kò ní ìwàC. Nítorí pé ó máa ń ṣooreD. Nítorí pé kò bímọCorrect Explanation Set-text question; this is a guess.
Ọdún wo ni "Awólọ́wọ̀ Hannah Ìdòwú Dídeolú" tó jẹ́ ìyàwó Awólọ́wọ̀ jáde láyé?
A. 1983B. 1966C. 2015Correct D. 1978Explanation Hannah Awolowo died in 2015.
Awólọ́wọ̀ jà fún ìsọkan Nàìjíríà àti fífi òpin sí ogun abẹ́lé ní ọdún ......
A. 1909B. 1967Correct C. 1920D. 1987Explanation The Nigerian civil war began in 1967.
Ẹ̀kọ́ pàtàkì tí a kọ́ nínú ìwé Awólọ́wọ̀ Akínkanjú Aṣíwájú ni pé ......
A. kí á kàwé dójú àmì nítorí ìwé ló mú kí ó gbayì ní gbogbo ayéCorrect B. kí akẹ́kọ̀ọ́ máa ṣe ìranù kiriC. kí a máa ṣe yàùúD. kí á fara balẹ̀ jà ọlẹExplanation The book teaches the value of education.
Ẹ̀kọ́ tí a kọ́ nínú ìwé "Èmi lọkọ ìyá wọn" ni pé ......
A. kí á máa sọ òtítọ́, olótìítọ́ kì í kú sípò ìkàCorrect B. kí á máa ṣe màdàrúC. kí á gbọyè nínú iró pípaD. kí á máa fàrí olóríExplanation Set-text question; this is a guess.
Ẹni tí ó jẹ́ olú ẹ̀dá ìtàn nínú ìwé "Èmi lọkọ ìyá wọn" ni ......
A. Dagunró ÌṣọláCorrect B. Làmbè BéyíokúC. Gbádébọ̀D. Títílayọ̀Explanation Set-text question; this is a guess.
Ta ni ó sọ pé òun ni ọkọ ìyá wọn nínú ìwé "Èmi lọkọ ìyá wọn"?
A. BílíkámínùB. DagunróCorrect C. Mobọ́láájí ỌkínD. Ayọ̀délé GbádégẹsinExplanation Set-text question; this is a guess.
Nínú ìtàn "Ìjà ọ dọlá" ẹni tí Ayọ̀mídé fẹ́ ẹ́ fẹ́ ni ......
A. OyèwọléCorrect B. OlúwọléC. OkétádéD. JídéExplanation Set-text question; this is a guess.
Orúkọ bàbá tí ó máa ń sọ ìtàn fún àwọn ọmọọmọ rẹ̀ ní abẹ́ igi odán ní ìlú Akogun ni ......
A. TìjáníB. Ayọ̀mídéC. ÀdàbàD. Ayédọgbọ́nCorrect Explanation Set-text question; this is a guess.
Nínú ìtàn "Ajá tó bá fẹ́ sọnù" ẹni tí ó jẹ́ ajá tó sọnù tí kò gbọ́ fèrè ọlọ́dẹ ni ......
A. FáróhùnbíCorrect B. ÀkànbíC. FárèmíD. OyètúndéExplanation Set-text question; this is a guess.
Nínú ewì "Ìbọ̀wọ̀fágbà" akéwì sọ pé ọmọ tó bá fẹ́ lu àlùyọ gbọ́dọ̀ ...... fún àwọn aṣíwájú.
A. fa wàhálàB. teríbaCorrect C. rí àgbà finD. paróExplanation The poem teaches respect and bowing to elders.
Nínú ewì àpilẹ̀kọ Ajímọ̀fun àti ewì míìràn "Irú iṣẹ́ wo ni akéwì pè ní iṣẹ́ AJÍMỌ̀FUN?"
A. Iṣẹ́ olùkọ́niCorrect B. Iṣẹ́ Nọ́ọ̀sìC. Iṣẹ́ ìmọ̀ ẹ̀rọD. Iṣẹ́ wọlẹ́wọlẹ́Explanation Set-text question; this is a guess.
Nínú ewì "ẹ̀kọ́ ṣe kókó" akẹ́kọ̀ọ́ tó bá kàwé ní àǹfààní láti di ...... àti ......
A. gómìnà àti Aàre orílẹ̀ èdèCorrect B. onínjàǹgbọ̀n àti onífwàhálàC. ọmọ iṣẹ́ àti alárinkáD. awakọ̀ àti agbẹ̀rọExplanation Education leads to high office.
Nínú ewì "Èrù àgbà" kí ni ohun tí ó dà bí ẹni pé arúgbó dé fìlà funfun sórí ní orí àgbà?
A. Fìlà aṣọ àlàB. Ewú orí àgbàCorrect C. Ọgbùn tí wọ́n dé sóríD. Aṣọ funfun tí wọ́n wọ̀Explanation Grey hair looks like a white cap.
Nínú ewì "Gbèsè ni kú" akéwì ń ka ikú gégé bí ......
A. ọ̀rẹ́ àtàtàB. alájọṣepọ̀ tó dáraC. ìpèkun ìrìnàjò ẹ̀dáCorrect D. ìdáwọ́ọ̀ ìdùnnúExplanation Death is seen as the end of man's journey.
Nínú ewì "Ẹ má bàgbà jẹ́" ẹni tó bá gbá ọpá lọ́wọ́ arúgbó ......
A. kò ní jẹunB. kò ní wọṣọC. kò ní wókòD. kò ní dàgbàCorrect Explanation He will not live to old age.
Sign up free to unlock Score tracking Practice history Saved questions Progress dashboard Personalized sessions Weak-topic breakdown…and/or go further with premium services and No Ads .