JSCE Yoruba Language 2024 Objective — Question 6
Question 6 of 100 from the Junior Secondary Certificate Examination (JSCE) Yoruba Language 2024 Objective paper, with the correct answer and a full explanation.
Advertisement
AKÀYÉ - EWÌ. Fi ọ̀rẹ́ ẹ̀ rẹ han mí, kí n sọ irú ẹni tí o jẹ́. Ẹgbẹ́kẹ́gbẹ́ máa ń bà ìwà rere jẹ́, akẹ́kọ̀ọ́ tí kò fetí sẹ́kọ̀ọ́ tí òbí àti olùkọ́ ń kọ́ ọ, a máa kó àbámọ̀ níkẹyìn. Má bá àwọn mu oògùn olóró, kì í jẹ́ kọ́dọ̀ọ̀ ó bẹ́gbẹ́ pé. Asìlò oògùn olóró, ti mú ọpọlọ ọdọ́ di aláàgánná sí gbóró. Nígbà tí oògùn olóró bá ń peṣẹ̀ lára ọdọ́, ìwàkiwà ni 'rú u wọn ń hù láwùjọ. Ọmíràn lè forí lu ọpọ́ iná bí abujigè. Ẹ̀mí ọmọ ènìyàn kì í jọ wọ́n lójú mọ́. Bí wọ́n bá gbé kinní ọ̀hún lura tán, ìwà wèrè ló kù tí wọ́n ó máa hù. Akẹ́kọ̀ọ́ tó bá ń lo oògùn olóró, kò lè kẹ́kọ̀ọ́ yege. Gbogbo abiamọ àti olùkọ́, ẹ jẹ́ ká ṣowópọ̀. Ká gbógun ti ìwà ìbàjẹ́, kí aṣìlò oògùn olóró kúrò láwùjọ wa. Kí ilé ayé ó lè rójú, káwùjọ wa ó tòrò nínú. Kójọ̀ ọ̀la àwọn ọmọ wa ó lè dára. Irú ẹgbẹ́ wo ni ó ń ba ìwà rere jẹ́? (Akáyé-Ewì: Fi ọ̀rẹ́ ẹ̀ rẹ han mí, kí n sọ irú ẹni tí o jẹ́)
- A. Ẹgbẹ́ onímọ̀
- B. Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́
- C. Ẹgbẹ́kẹ́gbẹ́Correct
- D. Ẹgbẹ́ Akẹ́kọ̀ọ́
Explanation
The poem warns about bad company, ẹgbẹ́kẹ́gbẹ́.
Advertisement
Sign up free to unlock
- Score tracking
- Practice history
- Saved questions
- Progress dashboard
- Personalized sessions
- Weak-topic breakdown
…and/or go further with premium services and No Ads.